chapter  12
Pípàdé ènìyàn ní ibùdó ò.kò. -òfurufú ní Èkó Meeting someone at Lagos airport
Pages 12

Kimberly is expecting her sister from the U.S.A. who will be visiting her in Nigeria. She wants Tunji to drive to Lagos with her to pick up her sister at the airport.

KIMBERLY: Túnjí, ßé o rántí pé oΩ$la ni àbúrò mi Carla máa dé láti New York?